Home Music Beautiful Nubia – Tiwalanse Ft. the Roots Renaissance Band

Beautiful Nubia – Tiwalanse Ft. the Roots Renaissance Band

0

Beautiful Nubia – Tiwalanse Ft. the Roots Renaissance Band

  • Artist: Beautiful Nubia
  • Featuring: the Roots Renaissance Band
  • Album: Táabákú
  • Released: 2016
  • Duration: 03:50

Download Beautiful Nubia – Tiwalanse ft. the Roots Renaissance Band Mp3
Hit-maker, Beautiful Nubia has released his highly anticipated single, “Tiwalanse.” The song is available on all streaming platforms.

Beautiful Nubia collaborates with serial hitmaker the Roots Renaissance Band, who makes a huge contribution to the song.

This is Beautiful Nubia‘s debut single for the year 2016 serves as a follow up to his previously released tune which is still doing well on various music charts.

 

Listen and share your thought below:

Beautiful Nubia – Tiwalanse lyrics

Wò wọn o, bí wọn ṣe nwò wá o, wọn ṣe bá ò l’óye
Ṣébí, tiwa l’à wá ń ṣe o
A tí fi’pò sílẹ’ f’ónípò, a fì’jà sílẹ’ f’álágbára
Tiwa l’à wá ń ṣe ò e

Kò s’óun tó ń bọ’ l’ókè n’ílẹ’, tó lè já wa l’áyà o
Ṣèbí t’ọba l’à wá ń ṣe o
A tí f’ìrẹ’lẹ’ ṣ’ọlá, a fì’tẹ’lọ’rùn ṣ’aṣọ
T’ọba l’à wá ń ṣe ò e

Kò s’óun tó ń bọ’ l’ókè n’ílẹ’ l’áyé, tí ó bà wá l’ẹ’rù
Ṣèbí tiwa l’à wá ń ṣe ò e

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here