Slimcase x Zlatan – “Pongilah” (Lyrics)

Slimcase x Zlatan – “Pongilah” (Lyrics)
Slimcase x Zlatan – “Pongilah” (Lyrics)
x – “Pongilah” (Lyrics)

AUDIO DOWNLOAD

[Intro]
Oya ma lo sunn,
Ko le sun yara ti ko ni lekun, ewuree wo be lo sun….
Ahh! My blood, my blood
Fresh!
Astalivi give them

[Verse 1 – ]
Okay, o ti ko si owo aye, (o ti ko si owo aye)
O ti wo’nu IG (Ah! o ti wo’nu IG)
O’n ti wa content,
O’n ti wa repost (O fe wa repost)
O tin gbon’di gbuse,
So idi gegege, idi gbonlebe gede
Idi’wese

[Chorus]
Awon omo isin pongilah kan le la,
Awon omo isin pongilah pongilah (Pongi)
Awon omo isin Pongilah kan le la,
Awon omo isin pongilah pongilah pongilah
Awon omo isin pongilah kan le la,
Awon omo isin pongilah pongilah
Awon omo isin Pongilah kan le la, (won pongi)
Awon omo isin pongilah pongilah ponwon la

HOT:  Psychic – Opoor (Plenty) ft. Zlatan

[Verse 2]
Otunba lamba, (Otunba lamba)
Won l’oti tun mugbe le (o fe mu gbe le)
O’n ti’n ta won, ta won, bi won shey won shey da’ko ni
Enu e shey wa n yo, s’olo ijabe ni,
Ara to ma san pawon n fagbo lowo oh
Fagbo ti e, kin fa temi,
k’eruku igbo kan ma lo Di’kan lo’wo oh
(…Baba) Coaste, coaste, coaste, coaste
Omi oyan lo’dun ju, e ma wo isu obo o ga ju
Omi oyan lo’dun ju, e ma wo isu obo o ga ju

[Chorus]
Awon omo isin pongilah kan le la,
Awon omo isin pongilah pongilah (Pongi)
Awon omo isin Pongilah kan le la,
Awon omo isin pongilah pongilah pongilah
Awon omo isin pongilah kan le la,
Awon omo isin pongilah pongilah
Awon omo isin Pongilah kan le la, (won pongi)
Awon omo isin pongilah pongilah ponwon la

HOT:  Larry Gaaga x Davido – Work (Lyrics)

[Verse 2 – Ibile]
Shebi Oloun lo da obo, (obo)
Eniyan lo de da dido
Wa fe lo fun e wo, iwo lo ma jawon pe iwo ko ni iko
Di e ni omo okunrin se ko’to,
Kini yen se o ni dido
O ni la ti kan left and right, k’an mo pe iwo gan set arrow
Igboro ni mi omo Havana, e le fe mi pa (Never)
Mi need la ti je Jay Jay, ki e to mo pe omo igboro ni mi, pe mo clever
Omo ogbon, omo ogbon, eja to wa ninu odo e le je tan (bawo ni e se fe si)
Lamba e le gbo tan,
Ibile lo confirm e, Iya eh
Astalivi

HOT:  Skiibii – “Somebody” ft. Kizz Daniel (Lyrics)

[Outro]
Oya ma lo sunn, (mo ni ma lo sun)
Ko le sun yara ti ko ni lekun, ewuree wo be lo sun….
(Ahhh curtain lo fisii)

Okay

Egeregetuma
Abarakatuma
Odoo o baby
Ijo makosa
Shey o le gbe iya yen
Shey enu e bo
,
Oya dagboro, dagbobi

Its STG

Damn!

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.