Home Music Gospel Music Sola Allyson Obaniyi – Adura Ololufe

Sola Allyson Obaniyi – Adura Ololufe

0

Sola Allyson Obaniyi – Adura Ololufe

  • Artist: Sola Allyson Obaniyi
  • Album: Adun
  • Released: 2023
  • Duration: 06:04

Download Sola Allyson Obaniyi – Adura Ololufe Mp3

The award-winning Gospel songwriter, Sola Allyson Obaniyi comes through with this new masterpiece soundtrack for his fan listening pleasure.

The original recording is a version of one of Sola Allyson Obaniyi‘s popular songs that was included on his sophomore studio album, which was titled Adun.

Listen and share your thought below:

Sola Allyson Obaniyi – Adura Ololufe lyrics

Adura mogba fun e ololufe mi
Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi
Oo ni kagbako l’aye oo ni r’ogun akoba
Oo ni s’irin l’aye be oo ni t’oju ile mole
Ainif’okanbale o ni y’odo re lailailailailai
Oo ni m’osi l’aye, aye re a ma dara si
Ife eledumare ree e ooo ore mi
O fewa fun re, o fewa f’ayo taa ba barawa s’otito
Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s’ise
Iranse alaanu re wa pelu t’emi nwon njo rin po ni

Ibaase ‘wo layo pupo latagbala eledumare wa inu oluwa aa dun si

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here