Home Music Gospel Music Sola Allyson Obaniyi – Akosile

Sola Allyson Obaniyi – Akosile

0

Sola Allyson Obaniyi – Akosile

  • Artist: Sola Allyson Obaniyi
  • Album: Eji Owuro Soundtrack
  • Released: 2023
  • Duration: 05:44

Download Sola Allyson Obaniyi – Akosile Mp3

Nigerian hit-maker, Sola Allyson Obaniyi serves up his new single, “Akosile,”. The song is available on all streaming platforms.

The song is a mind-blowing song by Sola Allyson Obaniyi, who has recently re-entered the mainstream of the music industry.

Listen and share your thought below:

Sola Allyson Obaniyi – Akosile lyrics

Akosile ti duro akosile o le tase oun toluwa base eda kan kole yi
Pada ibi ori n gbe ni lo kese ma si ni lona oun to wun eleduwa lo le
Yan fun wa atibi atire ton sele lala eda kole ye e e akosile ti duro
Kole tase o o o, ayanmo eda ti duro kirakita o dola laye gbogbo eto
Olorun kose ni tole ba tun to gbogbowa lan sare kiri pe ka lola ka
Jeniyan sugbon ta lole mo ibi ori dawun si atibi atire ton sele lala
Eda kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se,
Wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye
Mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.
Kadara eda ti duro ife eleda o le ye lai ona ti o ba wun olorun oun
Lole mu ese eda to ori e o dade ofe jo ba o wa n ba yanmo jijakadi
Boti wun e ni to dale lose n foyin si atibi atire ton sele lala eda

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here