Home Music Sola Allyson Obaniyi – Temisan

Sola Allyson Obaniyi – Temisan

0

Auto Draft

  • Artist: Sola Allyson Obaniyi
  • Album: Adun
  • Released: 2023
  • Duration: 06:24

Download Sola Allyson Obaniyi – Temisan Mp3

Nigerian singer-songwriter, Sola Allyson Obaniyi unleashes his anticipated single named ‘Temisan‘. The song is available on all streaming platforms.

Temisan was released in the year 2023 by the musical artist in an effort to satisfy the musical appetites of his devoted fans.

The original recording is a version of one of Sola Allyson Obaniyi‘s popular songs that was included on his sophomore studio album, which was titled Adun.

Listen and share your thought below:

Sola Allyson Obaniyi – Temisan lyrics

Ibukun orun ni ma a rigba, oju ire nma ri o
Ma a rin ire ma fadun sóla; emi a firorun saye mi
Bóti wu ko ri ma mori dele, ile ire adun a’toro
Motenu more o mo ri mu, te mi san si re o temi (ma) san o REPEAT

1.Ile aye yi o kun fun ja, jeje mode mo de ba ja
Wen wen mo ke ija mo ba; abi ki lomo se t’o firi ja
Atiwa ateyin ko rorun rara; ohun to fi ya je ni lo pon ni loju,
Iya o ye ye kómo je lógbomo sanle
Mo mona mi pon mo rin titi ti ase oba ok emo ohun ma a da,
Lófi mu mi rinna ti mo gba debi, eni to nigba lóseto aye mi
Mo rin rin titi mo déle ire

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here